0:00/???
  1. Ore Jesu

From the recording Ore Jesu

Your price

Ore Jesu

Track download

Please choose a price: $ USD ($1.99 or more)

Please pay at least $1.99

or close

Ore Jesu, literarily means God's Goodness.
Enjoy!

iTunes - http://apple.co/1o6CwcB
Spotify - http://spoti.fi/1RwheAZ


©LEXISUGAR MUSIC GROUP 2015

Lyrics

Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore Baba mi o
Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore re

Sheb'iwo lo ni gbo gbo orun o
Sheb'iwo lo ni gbo gbo aiye
Egberunahun ko to fun yin o o
Fun Gbo gb'ore t'o se

Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore Baba mi o
Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore re

Opolopo lo ti ku
Opolopo lo ti lo o
But it's in you I live and move and have my being
Baba you too much o

Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore Baba mi o
Kini ma fi san fun ore Jesu
Kini ma fi san fun ore re

Sheb'iwo lo ni gbo gbo orun o
Sheb'iwo lo ni gbo gbo aiye
Egberunahun ko to fun yin o o
Fun Gbo gb'ore t'o se